top of page
Resources For Yorùbá Learners
Yorùbá Textbooks
Reference Texts
Please reload
Literary Texts
Erée Géle
Ọgbọ́n orí tí ó péye àti àròjinlẹ̀ tó pinmirin ní Òǹkọ̀wé Ṣegun Ṣóẹ̀tán fi gbé ìwé ìtàn àròsọ yìí kalẹ̀. Ojúlówó èdè Yorùbá ní ó sí fi pèèlò rẹ̀. Àwọn ẹwà èdè Yorùbá ló ń ṣe gbérùmi-sọ̀mí nínú ìwé náà. Ó yá, ẹ gbà kẹ́ẹ tọ́ọ wò. Ire o!
Oyin inú Àpáta
Ìwe àkàgbádùn ní Oyin Inú Àpàta. Ó jẹ́ ìwé ìtàn àròsọ tí Ọ̀mọ̀wé Olúṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán fí ọgbọ́n inú àti ète ìmọ́ lítíréṣọ̀ gbé kalẹ̀. Ìwé yìí wúlò fún ẹni gbogbo, yálà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga girama tàbí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yunifásitì.
Please reload
bottom of page